Only logged in customers who have purchased this product may leave a review.
Bí imú Ìjàpá ṣe rí kọ́ńbó (Yoruba Language)
€0.00
Ní ìgbà kan, Ìjàpá àti Ọ̀kẹ́rẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́. Ní ọjọ́ kan lẹ́yìn oúnjẹ, Ọ̀kẹ́rẹ́ bi Ìjàpá, “Ọ̀rẹ́ mi, ọjọ́ ọjà ti fẹ́ dé ṣùgbọ́n a kò ní owó. Irú iṣẹ́ wo ni a lè ṣe láti pa owó?”
—————————————————————
Reading Level: 3
Download for free and let your children have the true flavour of your mother tongue.
Reviews
There are no reviews yet